Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 32:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Àwọn ọmọ Rúbẹ́nì àti àwọn ọmọ Gádì, tí wọ́n ní ẹran ọ̀sìn àti ohun ọ̀sìn rí wí pé ilé Jásérì àti Gádì dára fún ohun ọ̀sìn.

2. Nígbà náà wọ́n wá sí ọ̀dọ̀ Mósè àti Élíásárì àlùfáà àti sí olórí gbogbo ìlú, wọ́n sì wí pé,

3. “Átarótì, Díbónì, Jásérì, Nímírà, Hésíbónì, Élíálì, Sébámù, Nébò, àti Béónì.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 32