Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 31:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì mú gbogbo obìnrin Mídíánì ní ìgbékùn àti àwọn ọmọ kékeré wọn, wọ́n sì kó gbogbo ohun ọ̀sìn wọn àti gbogbo agbo ẹran wọn àti gbogbo ẹrù wọn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 31

Wo Nọ́ḿbà 31:9 ni o tọ