Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 30:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Tí ó bá sì ní ọkọ lẹ́yìn ìgbà tí ó jẹ́ ẹ̀jẹ́ tàbí lẹ́yìn ìgbà tí ó sọọ̀rọ̀ kan láti ẹnu rẹ̀ jáde nínú èyí tí ó fi de ara rẹ̀ ní ìdè,

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 30

Wo Nọ́ḿbà 30:6 ni o tọ