Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 30:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

tí baba rẹ̀ bá sì gbọ́ ẹ̀jẹ́ rẹ̀ tàbí ìdè rẹ̀ tí kò sì sọ nǹkan kan sí i, kí gbogbo ẹ̀jẹ́ rẹ̀ kí ó dúró àti gbogbo ìdè tí ó fi de ara rẹ̀ yóò sì dúró.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 30

Wo Nọ́ḿbà 30:4 ni o tọ