Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 30:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n tí ọkọ rẹ̀ bá sọ wọ́n dasán, nígbà tí ó gbọ́, nígbà náà kò sí ẹ̀jẹ́ tàbí ìdè tí ó ti ẹnu rẹ̀ jáde tí yóò dúró, ọkọ rẹ̀ ti sọ wọ́n dasán, Olúwa yóò tu sílẹ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 30

Wo Nọ́ḿbà 30:12 ni o tọ