Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 3:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí o sì gba àwọn ọmọ Léfì dípò gbogbo àkọ́bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí o sì gba gbogbo ẹran ọ̀sìn àwọn ọmọ Léfì fún mi dípò gbogbo àkọ́bí àwọn ẹran ọ̀sìn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Èmi ni Olúwa.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 3

Wo Nọ́ḿbà 3:41 ni o tọ