Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 3:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àpapọ̀ iye àwọn ọmọ Léfì tí a kà gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pa á láṣẹ fún Mósè àti Árónì gẹ́gẹ́ bí ìran wọn, pẹ̀lú gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ọmọ oṣù kan ó lé jẹ́ ẹgbàá mọ́kànlá (22,000).

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 3

Wo Nọ́ḿbà 3:39 ni o tọ