Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 29:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Àti ní ijọ́ kejì ni kí ẹ̀yin kí ó fi ẹgbọ̀rọ̀ akọ màlúù méjìlá, àgbò méjì àti ọ̀dọ́ àgùntàn mẹ́rìnlá ọlọ́dún kan aláìlábùkù rúbọ.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 29

Wo Nọ́ḿbà 29:17 ni o tọ