Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 29:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Ní ọjọ́ kìn-ín-ní, oṣù keje, kí ẹ ní àpéjọ mímọ́, ẹ kò gbọdọ̀ ṣe iṣẹ́ kankan. Ọjọ́ ìfúnpè ni ó jẹ́ fún yín.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 29

Wo Nọ́ḿbà 29:1 ni o tọ