Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 28:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ẹ mú ẹbọ sísun ẹgbọrọ màlúù méjì, àgbò kan àti akọ ọ̀dọ́ àgùntàn méje ọlọ́dún kan gẹ́gẹ́ bí òórùn dídùn fún Olúwa.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 28

Wo Nọ́ḿbà 28:27 ni o tọ