Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 28:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ẹbọ ohun mímu wọn jẹ́ ààbọ̀ òṣùwọ̀n hínì ti ọtí wáìnì, fún akọ màlúù kan, àti ìdámẹ́wàá òṣùwọ̀n hínì fún àgbò kan àti ìdámẹ́rin òṣùwọ̀n hínì fún ọ̀dọ́ àgùntàn kan. Èyí ni ẹbọ sísun tí wọn ó máa rú ní oṣù kọ̀ọ̀kan nínú ọdún.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 28

Wo Nọ́ḿbà 28:14 ni o tọ