Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 25:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ni Ísírẹ́lì ṣe darapọ̀ mọ́ wọn tí wọ́n sì jọ ń sin Báálì ti Péórì. Ìbínú Olúwa sì ru sí wọn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 25

Wo Nọ́ḿbà 25:3 ni o tọ