Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 23:29-30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

29. Bálámù sọ pé, “Kọ́ pẹpẹ méje fún mi níbí kí o sì pèsè akọ màlúù àti àgbò fún mi.”

30. Bálákì sì ṣe bí Bálámù ti sọ fún un, ó sì gbé akọ màlúù kan àti àgbò lórí pẹpẹ kọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 23