Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 23:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bálámù ṣo fún Bálákì pé, “Dúró níbí ní ẹ̀gbẹ́ ẹbọ rẹ nígbà tí mo bá lọ pàdé rẹ̀ níbẹ.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 23

Wo Nọ́ḿbà 23:15 ni o tọ