Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 22:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì Bálákì gbé Bálámù lọ sí òkè Báálì, láti ibẹ̀ ló ti rí apákan àwọn ènìyàn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 22

Wo Nọ́ḿbà 22:41 ni o tọ