Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 22:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rí mi ó sì yà kúrò fún mi lẹ́ẹ̀mẹ́ta yìí. Tí ó bá jẹ́ wí pé kò yà kúrò. Èmi kì ìbá ti pa ọ́ pátapáta nísinsìnyìí, ṣùgbọ́n Èmi yóò sì dá òun sí.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 22

Wo Nọ́ḿbà 22:33 ni o tọ