Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 22:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ sọ fún Bálámù pé, “Ṣé mi kì í ṣe kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ ni, tí o máa ń gùn ní gbogbo ìgbà, láti ìgbà pípẹ́ wá? Ǹjẹ́ mo hu irú ìwà báyìí sí ọ rí?”“Rárá,” Ó dáhùn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 22

Wo Nọ́ḿbà 22:30 ni o tọ