Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 22:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rí ángẹ́lì Olúwa, ó lẹ̀ mọ́ ẹ̀gbẹ́ ògiri, ó sì rún ẹsẹ̀ Bálámù mọ́ ògiri. Nígbà náà, ó tún nàá, lẹ́ẹ̀kan sí i.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 22

Wo Nọ́ḿbà 22:25 ni o tọ