Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 21:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ibẹ̀ ni wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ rìn dé Béérì, èyí ni kànga tí Olúwa sọ fún Mósè, “Kó àwọn ènìyàn jọ èmi ó sì fún wọn ní omi.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 21

Wo Nọ́ḿbà 21:16 ni o tọ