Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 20:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ṣùgbọ́n nígbà tí a sunkún sí Olúwa, ó gbọ́ ẹkún wa, ó sì rán ańgẹ́lì kan sí wa, ó sì mú wa jáde láti Éjíbítì.“Báyìí àwa wà ní Kádésì, ìlú tí ó wà ní ẹ̀gbẹ́ ilẹ̀ rẹ.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 20

Wo Nọ́ḿbà 20:16 ni o tọ