Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 2:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn tí a yàn sí ibùdó Júdà, gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn àpapọ̀ iye wọn jẹ́ ẹgbàá mẹ́taléláàdọ́rin ó lé irínwó (186,400). Àwọn ni yóò kọ́kọ́ ṣáájú.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 2

Wo Nọ́ḿbà 2:9 ni o tọ