Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 2:19-23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

19. Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ọ̀kẹ́ méjì-ó-lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta. (40,500).

20. Ẹ̀yà Mánásè ni yóò tẹ̀lé wọn. Olórí Mánásè ni Gàmálíélì ọmọ Pedasúrì.

21. Iye ìpín rẹ̀ ni ẹgbàá mẹ́rìndínlógún-ó-lé-igba (32,200).

22. Ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì ni yóò tẹ̀ lé e. Olórí Bẹ́ńjámínì ni Ábídánì ọmọ Gídíónì.

23. Iye ìpín rẹ̀ ni ẹgbàá mẹ́tadínlógún ó lé egbéje (35,400).

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 2