Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 2:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ènìyàn tí a yàn sí ibùdó Rúbẹ́nì, gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn àpapọ̀ iye wọn jẹ́ ẹgbàá márùndínlọ́gọ́rún ó lé àádọ́tàlélégbéje (151,450). Àwọn ni yóò jáde sìkéjì.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 2

Wo Nọ́ḿbà 2:16 ni o tọ