Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 19:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹni tó wà ní mímọ́ ni yóò kó eérù ọ̀dọ́ màlúù náà lọ sí ibi tí a yà sí mímọ́ lẹ́yìn ibùdó. Kí gbogbo ìjọ ènìyàn Ísírẹ́lì kó o pamọ́ fún lílò fún omi ìwẹ̀nùmọ́. Ó jẹ́ ìwẹ̀nùmọ́ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 19

Wo Nọ́ḿbà 19:9 ni o tọ