Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 18:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n bá pé oṣù kan, o gbọdọ̀ rà wọ́n padà ní iye owó ìràpadà tí í ṣe ṣékélì márùn ún fàdákà, gẹ́gẹ́ bí iye ṣékélì ibi mímọ́ tí ó wọn ìwọn ogún (20) gérà.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 18

Wo Nọ́ḿbà 18:16 ni o tọ