Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 18:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èyí tún jẹ́ tìrẹ pẹ̀lú: ohunkóhun tí a bá yà sọ́tọ̀ lára ẹ̀bùn ọrẹ fífì àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Mó fún ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ ọkùnrin àti ọmọ rẹ obìnrin gẹ́gẹ́ bí ipin tí yóò máa ṣe déédé nínú ìdílé rẹ, tí o bá wà ní mímọ́ ni o le jẹ ẹ́.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 18

Wo Nọ́ḿbà 18:11 ni o tọ