Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 17:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kí o sì gba ọ̀pá méjìlá lọ́wọ́ wọn, ọ̀kọ̀ọ̀kan lọ́wọ́ olórí ìdílé ẹ̀yà ìran wọn, kọ orúkọ ènìyàn kọ̀ọ̀kan sí ara ọ̀pá rẹ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 17

Wo Nọ́ḿbà 17:2 ni o tọ