Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 16:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì sọ fún Árónì pé, “Mú àwo tùràrí, kí o fi iná sí i lórí pẹpẹ, fi tùràrí sínú rẹ̀, kí o sì tètè mu lọ sí àárin ìjọ ènìyàn láti ṣètùtù fún wọn nítorí pé ìbínú Olúwa ti jáde, àjàkálẹ̀-àrùn sì ti bẹ̀rẹ̀.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 16

Wo Nọ́ḿbà 16:46 ni o tọ