Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 16:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ẹnì kọ̀ọ̀kan yín mú àwo tùràrí, kí ó sì fi tùràrí sínú rẹ̀, kí gbogbo rẹ̀ jẹ́ àádọ́tàlénígba àwo tùràrí (250) kí ẹ sì ko wá ṣíwájú Olúwa. Ìwọ àti Árónì yóò mú àwo tùràrí wá pẹ̀lú.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 16

Wo Nọ́ḿbà 16:17 ni o tọ