Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 15:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọ̀rọ̀, kí o sọ fún wọn pé: ‘Títí dé àwọn ìran tó ń bọ̀ ni kí wọn máa ṣe wajawaja sí etí aṣọ wọn, kí wọn sì fi okùn tẹ́ẹ́rẹ́ aláwọ̀ búlúù sí wajawaja kọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 15

Wo Nọ́ḿbà 15:38 ni o tọ