Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 15:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àléjò kan bá ń gbé láàrin yín ní gbogbo ìran yín, bí irú ẹni bẹ́ẹ̀ bá fẹ́ mú ọrẹ àfinásun bí òórùn dídùn wá fún Olúwa, gbogbo bí ẹ bá ṣe ń ṣe náà ni kí ó ṣe.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 15

Wo Nọ́ḿbà 15:14 ni o tọ