Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 11:5-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Àwa rántí ẹja tí à ń jẹ lọ́fẹ̀ẹ́ ní Éjíbítì, apálá, ègúsí, ewébẹ̀ àlùbọ́sà àti àwọn ẹ̀fọ́ mìíràn

6. Ṣùgbọ́n báyìí gbogbo ara wa ti gbẹ, kò sí ohun mìíràn láti jẹ àfi mánà nìkan tí a rí yìí!”

7. Mánà náà dàbí èso koriáńdérì, ìrísí rẹ̀ sì dàbí oje igi.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 11