Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 11:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì gbọ́ tí àwọn ènìyàn ń sunkún ní gbogbo ìdílé wọn, oníkálukú ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ tirẹ̀. Olúwa sì bínú gidigidi. Inú Mósè sì bàjẹ́ pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 11

Wo Nọ́ḿbà 11:10 ni o tọ