Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 9:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí gbogbo èyí, a ń ṣe àdéhùn tí ó fẹṣẹ̀múlẹ̀, a sì kọ ọ́ sínú ìwé, àwọn olórí ọmọ Léfì àwọn àlùfáà wọn wa sì fi èdìdì wọn dìí.”

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:38 ni o tọ