Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 9:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n dúró sí ibi tí wọ́n wà, wọ́n sì fi ìdámẹ́rin ọjọ́ kà nínú ìwé òfin Olúwa Ọlọ́run wọn, wọ́n sì tún fi ìdámẹ́rin mìíràn ní ìjẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti ní ṣíṣin Olúwa Ọlọ́run wọn.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:3 ni o tọ