Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 9:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ogójì ọdún ni ìwọ fi bọ́ wọn ní ihà; wọn kò ṣe aláìní ohunkóhun, aṣọ wọn kò gbó bẹ́ẹ̀ ni ẹṣẹ̀ wọn kò wú.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:21 ni o tọ