Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 9:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọ̀sán ìwọ daríi wọn pẹ̀lú òpó ìkúùkú àti ní òru ni ìwọ daríi wọn pẹ̀lú òpó iná láti fún wọn ní ìmọ́lẹ̀ ní ọ̀nà tí wọn yóò gbà.

Ka pipe ipin Nehemáyà 9

Wo Nehemáyà 9:12 ni o tọ