Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 8:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nehemáyà wí pé, “Ẹ lọ kí ẹ gbádùn oúnjẹ tí ẹ yàn láàyò kí ẹ sì mú ohun dídùn, kí ẹ sì mú díẹ̀ ránṣẹ́ sí àwọn tí kò ní. Ọjọ́ yìí, mímọ́ ni fún Olúwa wa. Ẹ má ṣe banújẹ́, nítorí ayọ̀ Olúwa ni agbára yín.”

Ka pipe ipin Nehemáyà 8

Wo Nehemáyà 8:10 ni o tọ