Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 5:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ fún wọn ní oko wọn, ọgbà àjàrà wọn, ọgbà ólífì wọn àti ilée wọn pẹ̀lú owó èlé tí ẹ ti gbà lọ́wọ́ọ wọn ìdá ọgọ́rùn-ún owó, oúnjẹ (ọkà), wáìnì túntún àti òróró tí ẹ ti gbà lọ́wọ́ọ wọn padà kíákíá.”

Ka pipe ipin Nehemáyà 5

Wo Nehemáyà 5:11 ni o tọ