Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 2:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni mo sọ fún wọn pé, “Ṣé ẹ rí wàhálà tí a wọ̀: Jérúsálẹ́mù wà nínú ìparun, ibodè rẹ̀ ni a sì ti fi iná jó. Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a tún odi Jérúsálẹ́mù mọ, àwa kò sì ní jẹ́ ẹni ẹ̀gàn mọ́”

Ka pipe ipin Nehemáyà 2

Wo Nehemáyà 2:17 ni o tọ