Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Ṣáńbálátì ará Hórónì àti Tòbáyà ará a Ámónì tí wọ́n jẹ́ ìjòyè gbọ́ nípa èyí pé, ẹnikan wá láti mú ìtẹ̀ṣíwájú bá àlàáfíà àwọn ará Ísírẹ́lì inú bí wọn gidigidi.

Ka pipe ipin Nehemáyà 2

Wo Nehemáyà 2:10 ni o tọ