Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 11:33-36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

33. Ní Háṣórì Rámà àti Gítaímù,

34. Ní Hádídì, Ṣébóimù àti Nébálátì,

35. Ní Lódì àti Ónò, àti ní àfonífojì àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà.

36. Nínú ìpín àwọn ọmọ Léfì ni Júdà tẹ̀dó sí Bẹ́ńjámínì.

Ka pipe ipin Nehemáyà 11