Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 11:30-35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

30. Ṣánóà, Ádúlámù àti àwọn ìletò o wọn, ní Lákísì àti àwọn oko rẹ̀, àti ní Ásékà àti awọn ìletò rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń gbé láti Bíáṣébà títí dé àfonífojì Hínómì.

31. Àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì láti Gébì ń gbé ní Míkímásì, Áíjà, Bétélì àti àwọn ìletò rẹ̀.

32. Ní Ánátótì, Nóbù àti Ánáníyà,

33. Ní Háṣórì Rámà àti Gítaímù,

34. Ní Hádídì, Ṣébóimù àti Nébálátì,

35. Ní Lódì àti Ónò, àti ní àfonífojì àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà.

Ka pipe ipin Nehemáyà 11