Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 11:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àti àwọn ẹlẹgbẹ́ ẹ wọn, ẹni tí ó ń ṣe iṣẹ́ ní tẹ́ḿpìlì jẹ́ ẹgbẹ̀rin ó lé mẹ́rinlélógún (822) ọkùnrin: Ádáyà ọmọ Jéróhámù, ọmọ Péláyà, ọmọ Ámísì, ọmọ Ṣakaráyà, ọmọ Pásúrì, ọmọ Málíkíjà,

Ka pipe ipin Nehemáyà 11

Wo Nehemáyà 11:12 ni o tọ