Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 11:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsinyìí àwọn olórí àwọn ènìyàn tẹ̀dó sí Jérúsálẹ́mù, àwọn ènìyàn tó kù sì dìbò láti mú ẹnì kọ̀ọ̀kan jáde nínú àwọn mẹ́wàá mẹ́wàá láti máa gbé ní Jérúsálẹ́mù, ìlú mímọ́, nígbà tí àwọn mẹ́sàn-án tó kù yóò dúró sí àwọn ìlúu wọn.

Ka pipe ipin Nehemáyà 11

Wo Nehemáyà 11:1 ni o tọ