7. Mésúlámù, Ábíjà, Míjámínì,
8. Mááṣáyà, Bílígáì àti Ṣémáyà.Àwọn wọ̀nyí ni àwọn àlùfáà.
9. Àwọn ọmọ Léfì:Jéṣúà ọmọ Aṣanáyà, Bínúyì ọ̀kan nínú àwọn ọmọ Hénédédì, Kádímélì,
10. àti àwọn ẹlẹgbẹ́ ẹ wọn: Ṣébánáyà,Hódáyà, Kélítà, Péláyà, Hánánì,
11. Míkà, Réhébù, Hásábáyà,
12. Ṣákúrì, Ṣérébáyà, Ṣébánáyà,
13. Hódáyà, Bánì áti Benínù.
14. Àwọn olórí àwọn ènìyàn:Párósì, Páhátí-Móábù, Élámù, Ṣátù, Bánì,
15. Búnì, Áṣígádì, Bébáyì.
16. Àdóníjà, Bígífáyì, Ádínì,
17. Átérì, Heṣekáyà, Áṣúrì,
18. Hódáyà, Háṣámù, Béṣáyì,
19. Hárífì, Ánátótì, Nébáyì,
20. Mágípíásì, Mésúlámù, Héṣírì