Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 10:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àwa, àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì àti àwọn ènìyàn náà ti dìbò láti pinnu ìgbà tí olúkúlùkù àwọn ìdílé yóò mú ọrẹ igi wá láti ṣun lọ́ríi pẹpẹ Olúwa Ọlọ́run wa sí ilé Ọlọ́run wa, ní àkókò tí a yàn ní ọdọọdún. Gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ sínú ìwé òfin.

Ka pipe ipin Nehemáyà 10

Wo Nehemáyà 10:34 ni o tọ