Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 10:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà tí àwọn ènìyàn àdúgbò bá mú ọjà tàbí oúnjẹ (ọkà) wá ní ọjọ́ ìsimi láti tà, àwa kò ní ràá ní ọwọ́ọ wọn ní ọjọ́ ìsimi tàbí ní ọjọ́ mímọ́ kankan. Ní gbogbo ọdún keje àwa kò ní ro ilẹ̀ náà, a ó sì pa gbogbo àwọn gbèsè rẹ́.

Ka pipe ipin Nehemáyà 10

Wo Nehemáyà 10:31 ni o tọ