2. Ṣeráyà, Aṣaráyà, Jeremáyà,
3. Páṣùn, Ámáráyà, malikíjà,
4. Hátúsì, Ṣebanáyà, málúkì,
5. Hárímù, Meremótì, Obadáyà,
6. Dáníẹ́lì, Gínétónì, Bárúkì,
7. Mésúlámù, Ábíjà, Míjámínì,
8. Mááṣáyà, Bílígáì àti Ṣémáyà.Àwọn wọ̀nyí ni àwọn àlùfáà.
9. Àwọn ọmọ Léfì:Jéṣúà ọmọ Aṣanáyà, Bínúyì ọ̀kan nínú àwọn ọmọ Hénédédì, Kádímélì,
10. àti àwọn ẹlẹgbẹ́ ẹ wọn: Ṣébánáyà,Hódáyà, Kélítà, Péláyà, Hánánì,
11. Míkà, Réhébù, Hásábáyà,