Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemáyà 1:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa, jẹ́ kí etíì rẹ sí sílẹ̀ sí àdúrà ìránṣẹ́ rẹ yìí, àti sí àdúrà àwọn ìránṣẹ́ rẹ tí wọ́n ní inú dídùn láti bọ̀wọ̀ fún orúkọ rẹ. Fún ìránṣẹ́ rẹ ní àṣeyọrí lónìí kí o sì síjú àánú wòó níwájú Ọkùnrin yìí,”Nítorí tí náà mo jẹ́ agbé-kọ́ọ̀bù ọba, nígbà náà.

Ka pipe ipin Nehemáyà 1

Wo Nehemáyà 1:11 ni o tọ